Powered By Blogger

Subscribe Now: RSS feed

Showing posts with label women. Show all posts
Showing posts with label women. Show all posts

Thursday, November 28, 2013

Ewì Ọmọge Ìwòyí - Girls of now-a-days





mọge ìwòyí o!!!
ẹ̀yin ni mò ń báwí, ẹ t’ẹ́tí kí  gb’ọ́rọ̀ nuù mi
Ẹ yáa gbọ́ mi yéké.
Àntí Bùkọ́lá, Tọ́sìn o lẹ́sẹ̀ tínínrín
Sììstá Jẹ́nífà lẹ́sẹ̀ pàlàbà, Fásílá o lẹ́sẹ̀ ẹe,
Àfi kí ẹ tọ́jú ki e tọ́tè, máa gbọ̀ndí kiri àdúgbò
Áwù, aṣ kù lọ́jà, èwo ni ti bóńfòèwo n taṣ pénpé kí ẹ dá,
Kò balẹ̀ le fi e
À ẹ ò mọ̀ pé aṣ àbúròo yín l wọ̀?
Ìbàdí ọmọge yín là ń wò l’òfẹ́ lófò,
Gbogbo ọmú rè é níta,  jọ̀wọ́  bòdíi yín o, ó ti súu wá í wò.
Níbi tí bùbá àti ìró tó gbáfẹ́ gbé wà,
Àmọ́ àkísà lẹ̀yín yàn láàyò.
Gbogbo ibi la ti ń bá ọ, bíi ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀
Ìwọ lónìí, ìwọ lánàá bí kún apọkọj
Wàá gbé dúdú, gbé pupa,
Bo ń gbé kúkúrú lò ń gbé gíga
Àti ọ̀dọ́ àt’ọkọ ilé, déédé ni
Ṣé kò kí ń rẹ̀ ọ́ ni? Ó rẹ̀ mí tì, é le è rẹ̀ mí lo fi ń e
Àtolátọ̀sí, àtoní wárápá, gbogbo wọn ló ń ebẹ̀,
ò kọ̀ kan, gbogbo ayé ní í gbé e sẹ́nu, kò yàtọ̀ sí síbí ilé ìjun
Àlàpà tó dnu ílẹ̀ran oríi ní í fi bẹ̀ e ‘lé
Tára bá bájẹ́ talára ní í dà, bí ọ̀rọ̀ àgbà
Ṣọ́ ọ e ọmọge fácitì, ìwọ ọmọ ilé ìwé gíga  ṣọ́ra e
Alágmọ ti bímọ, àìmọ́jó dọwọ́ọ yín 


The above ewì (a Yorùbá poem) talks about the indecent dressing among-st girls of now a days - ìwọ̀ kuwọ̀ láàríàwmọge ìwòyí

We look at western culture, imitate them and forget our own - àà òkèèrè là ń kọ́ e, tí a gbàgbée tiwa

We wear clothes worn by club strippers on the street - aṣ ilé ijó là ń wọ̀ kiri ìgboro

We no longer wear our Yorùbá attires (ò w aṣ ìbílẹ̀ wa mọ́). Prostitution and promiscuity is the other of the day - àgbèrè àti panágà ti gbàlú kan.


See the translation of the ewì below :


mọge ìwòyí o!!!
Pretty girls of now a days!!!

ẹ̀yin ni mò ń báwí, ẹ t’ẹ́tí kí  gb’ọ́rọ̀ nuù mi
Yes it is you am talking to, listen to my voice

Ẹ yáa gbọ́ mi yéké.
Better listen to me clearly.

Àntí Bùkọ́lá, Tọ́sìn o lẹ́sẹ̀ tíírín
Aunty Bùkọ́lá, Tọ́sìn the tiny leg

Sììstá Jẹ́nífà lẹ́sẹ̀ pàlàbà, Fásílá o lẹ́sẹ̀ ẹe,
Sister Jenifa the big leg, Fasilat the hen leg,

Àfi kí ẹ tọ́jú ki e tọ́tè, máa gbọ̀ndí kiri àdúgbò
All you know is to paint your eye and lips, shake ass about

Áwù, aṣ kù lọ́jà, èwo n bóńfòèwo laṣ pénpé kí ẹ dá,
When there are clothes in the market, which one is this short, small cloth that you wear,

Kò balẹ̀ l fi e
Not long enough

À ẹ ò mọ̀ pé aṣ àbúròo yín l wọ̀?
Or you don not know is your sister's?

Ìbàdí ọmọge yín là ń wò l’òfẹ́ lófò,
We see the waist of a beauty free of charge,

Gbogbo ọmú rè é níta,  bòdíi yín o, ó ti súu wá í wò.
The breasts are out, cover it, we are tired of looking.

Níbi tí bùbá àti ìró tó gbáfẹ́ gbé wà,
When we have nice bùbá and ìró,

Àmọ́ àkísà lẹ̀yín yàn láàyò.
But you chose to wear rags.

Gbogbo ibi la ti ń bá ọ, bíi ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀
You are everywhere just like the air

Ìwọ lónìí, ìwọ lánàá bí kún apọkọj
It is you today, you tomorrow

Wàá gbé dúdú, gbé pupa,
You date dark and fair skinned,

Bó ń gbé kúkúrú lò ń gbé gíga
As you date short men, so you date tall ones

Àti ọ̀dọ́ àt’ọkọ ilé, déédé ni
Boys and married men, its okay

Ṣé kò kí ń rẹ̀ ọ́ ni? Ó rẹ̀ mí tì, é le è rẹ̀ mí lo fi ń e
Don't you get tired? Never, you never get tired

Àtolátọ̀sí, àtoní wárápá, gbogbo wọn ló ń ebẹ̀,
Even patients of urinary infection, and epilepsy come close,

ò kọ̀ kan, gbogbo ayé ní í gbé e sẹ́nu, 
You don't mind, the world puts its mouth,

 yàtọ̀ sí síbí ilé ìjun
Not different from spoon of a restaurant

Àlàpà tó dnu ílẹ̀ran oríi ní í fi bẹ̀ e ‘lé
Broken wall that is open, any animal lives in it

Tára bá bájẹ́ talára ní í dà, bí ọ̀rọ̀ àgbà,
When the body get spoil, only the owner feels it

Ṣọ́ ọ e ọmọge fácitì, ìwọ ọmọ ilé ìwé gíga  ṣọ́ra e
Be careful, pretty university girl, you high school girl 


Alágmọ ti bímọ, àìmọ́jó dọwọ́ọ yín .
The masquerade agmọ has given birth to a child, it is left for the child to learn to dance.

What do you think about the ewì?

And don't forget to subscribe to this blog ;).

Visit YOUTUBE for the audio version.


Check out www.yobamoodua.org for more on Yorùbá education and information.

Friday, June 7, 2013

ÌYÀWÓ ILÉ ILẸ̀Ẹ YORÙBÁ (THE YORÙBÁ HOUSEWIFE)

yá ni wúrà iye bíye
tí a ò lè fowó rà,
Ó lóyún mi fóṣù msaan,
ó pọ̀n mi fọ́dún mta
ìyá ni wúrà iye bíye
tí a ò lè fowó rà"

<translation>
Mother is gold, expensive,
that money cannot buy
she carried me in her womb for 9 months
she back snuggled me for 3 years.
Mother is gold, expensive,
that money cannot buy


              .................

              .................

Ìyá- is the word for mother in Yorùbá. It is believed that the African mother, the Yorùbá woman is precious and must be adored, pampered (gbe gẹ̀gẹ̀) which is why my people say 'ì ni wúrà...' (mother is gold).


Again, to the Yorubas, the 9 months;oṣù msan pregnancy stage is not an easy task, not to mention the irora- pain, stress- ìnira on the ọjọ́ ìkúnlẹ̀: day of delivery (labour). 


She has a lot on her hand to do in the welfare of her child/children (ọmọ) , she breast feeds the child "á á fún ọmọ lọ́yàn",back snug the child "á á pọn sẹ́yìn", bathe it á wẹ̀ fún un  and care for it á tọ́ júu ẹ̀ even in the middle of the night; ọ̀gànj́ òru.

The poem my mother by Ann Taylor is not enough to show the worth iyì, strength agbára of the African Yorùbá mother.

This is why in Yorùbá land, the ìyá is regarded as the next after God. Any child who disobeys the mother automatically disobeys the creator. This can also be found in the christian philosophy as well as in Islam, both the Bible & Quran attest to this. 

Ìyàwó means wife in English, while ilé is the Yoruba word for house, home and to have a 'wife' is to have a mother who knows the value of child care, home keep to list a few.

The ìyàwó ilé is the housewife, who is most of the time expected to be in the home environment and not too far from the home where the ilé ìdáná, kitchen is her main spot. When not in the ilé ìdáná, she is in the market place; ọjà  selling her wares, which includes, aṣọ-òkè, òfì (clothing), agb̀n (basket), ìkòkò; clay pots and other goods.

The ìyàwó ilé on the other hand, is what the Yoruba tradition expects the wife to be in the ilé: house. She is expected to dáná/se oúnjẹ: cook for the family, see to their well being.

The major responsibilities of an ìyàwó ilé should do include: ọmọ bíbí, child bearing, ìtọjú ọmọ àti ọkọ: child care & husband pampering, iṣẹ́ ilé: house shores.

Apart from looking after children and the other duties of the ìyàwó ilé, it is her responsibility to inculcate the Yorùbá morals, ethics, values and norms in them (ìwà ọmọlúàbí, àà, ìé ilẹ́ Yorùbá ). Of which, ìtẹríba: respect/obedience for the bí: family, ọ̀rẹ́: friends, abálégbé: neighbours, alàgbà: elders, ẹgbẹ́: age mate, is of paramount importance (ó e kókó). 

Our people often say that "ọmọ gb́dọ̀ yàn kó yanjú, ó gb́dọ̀ jẹ ọmọlúàbí, tí a bíre, t́re, wò re" - a child must be nurtured with the proper ethical, moral, social manners and for this to happen, the mother would have done a great job for her children to be regarded as ọmọlúàbí or ọmọ tó gbà ẹ̀ḱ ilé (moral children).

As the house keeper- alámójúto ilé, nothing kept in her care must go amiss, she must be a good cook for her husband to love her, she washes the man's aṣọ, clothes with that of the children if they are still in a tender age.

If a housewife did not meet up with the expectations of the bí ọkọ: husband's family (in-laws), then arises complaints over everything she does. They will say 'ìyàwó kò mọ̀ ẹsẹ gbé'.

To be loved by her in-laws;bí ọkọ, she must care for and also have respect - ìtẹ́ríba for everyone even the youngest of them (àbúrò ọkọ). She calls the male - kùnrin 'brother' and female - obìnrin 'sister' using "ẹ" as a sign of respect when she addresses them.

Are you a housewife? What shores do you do which is not stated here? Do you think the housewife still work in this generation? 

Kí lo rò? Jẹ́ kí á gb́ ní pà ẹ̀

:)


Check out www.yobamoodua.org for more on Yorùbá education and information.