Subscribe Now: RSS feed

Friday, 28 June 2013

World Ṣàngó Festival 2013Ọba Ọ̀yọ́, ọba Làmídì Adéyẹmí kẹ́ta, n pè ọ́ sí ayẹyẹ ọdún Ṣàngó àgbáyé tí yóò wáyé nínú oṣù Ògún, tẹ ìpolówó òkè yìí kí ó darí rẹ.

Gbogbo yín lapé o!!!

The king of Ọ̀yọ́, ba Làmídì Adéymí 111 invites the world to the World Ṣàngó Festival in August, 2013. Click the above video to see the commercial.

Come one, come all!!!