Powered By Blogger

Subscribe Now: RSS feed

Friday, March 21, 2014

Ọpẹ́lọpẹ́ @twitter





Gba #tweet r àkọ́kọ́ níbi




Ọpẹ́lọpẹ́ @twitter, ọpẹ́lọpẹ́ ayélujára, ẹ̀rọ ayárabíàṣá ìgbàlódé tó ń gbọ́rọ̀káyé pẹ̀lú ìrọ̀rùn. 
Kí lọ fẹ́ tí ò sí lóríi ayélujára. 

Ọpẹ́lọpẹ́ @twitter, lọ́wọ́ kan là ń mọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ láwùjọ, ẹsẹ̀ kan náà ni gbogbo ayé  ń gbọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ki ṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé. 

Tẹ́lẹ̀, nígbà tí kò sí ayélujára, ẹni ò ní àpótí àfowólé ẹ̀rọ amóhùmáwòrán ilẹ̀ òkèèrè ò lè mọ ohun ń lọ lágbàáyé. Ìròhìn ìṣẹ̀lẹ̀ onírúurú ni à ń rí lóríi ẹ̀rọ agbọ́rọ̀káyée @twitter, ọpẹ́lọpẹ́ ayélujára. 

Àti pé, ààyè ṣí sílẹ̀ gbagada fún gbogbo ọmọ aráyé láti wà lóríi ayélujára. Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló ń fi @twitter ṣe jẹunjẹun, ibẹ̀ ni wọ́n ti ń rí oúnjẹ oòjọ́ tí wọ́n fi ń gbé jẹ. 

Ọpẹ́lọpẹ́ @twitter, ọpẹ́lọpẹ́ ayélujára, èmi náà ò bá máti wà níbi.





Thursday, February 13, 2014

Why Masquerade?


 

Egúngún Òndó

Yorùbá belief that somehow, there's ìbáṣepọ̀; relationship that takes place (láàrinbetween the living ará ayé and the dead - ará ọ̀run. It is said that ará àlàdé ọ̀run (people of the dead) visits ayé; earth sometimes. 

When the dead is buried - bí a bá sín ní kú, the corpse in the long run turns into earth, bópẹ́ bóyá eèpẹ̀ á gba ara but ṣùgbọ́n the egúngún (bones) will be left in the grave; sàárè. The spirit ẹ̀mí of the dead person òkú is brought back to life through egúngún

The word egúngún is derived from egúngún; bone or skeleton. It implies that when one dies, one automatically becomes egúngún; egúngún as the body rots in the earth; ilẹ̀.

Nítẹ́síwájú
; in furtherance, my people say "bí ará ayé ṣń ṣàdúrà fún ará ọ̀run bẹ́ẹ̀ lará ọ̀run ń ṣàdúrà fún ará ayé " - the living pray for the dead, so the dead pray for the living. Which is why you hear Yorùbá's say "orí ìyá mi lọ́run má sùn o" - my mother in heaven thou should not sleep (late mother in heaven help me) or "ẹlẹ́dàá bàbá mi gbèmí, o ò gbọdọ̀ sùn lọ́run  o" - my father’s maker (soul) please do not sleep in heaven.



The Yorùbá people remember their late ones by making sàárà (usually àkàrà) which will be distributed to the living. A reason why almost all homes have one eégún or the other.

Ọjọ́ tí à ń rántí àwọn òkú ọ̀run làwọn eégún lóríṣiríṣi ma ń jáde (wá sí ayé), láti wá f'ìyà jẹ ẹni ibi, tí ẹni ire yóò gba ìbùkún - the day that the Yorùbá  remember the late is when eégún comes to town.

You don't expect an ará ọ̀run; masquerade to speak like the living, which is why you hear the ohùn; voice of the masquerade sound like kọ̀nkọ̀ lálẹ̀ odò - a frog under water. Once you hear the voice, no one tells you it's an eégún speaking.

Ònpìtàn; historian sọ fún wa wípé said that, Ẹ̀ṣà Ọ̀gbín Ológbojò is the first egúngún to display in the ẹ̀kú; eégún atire lórílẹ̀ ayé - on earth. The historians, said that it is a man named Ọlọ́wọjọ̀n Kújẹ́nrá ará Agbọ́ṣọ̀kun that own the ẹ̀kú eégún 

Whenever, Ẹ̀ṣà Ọ̀gbín Ológbojò wears the masquerade attire (ẹ̀kú or agọ̀ egúngún), he praises himself with ewì; poem as he ; dances kiri about nínú in agọ̀ the regalia.


The poem ewì alóhùn tí Ẹ̀ṣà Ọ̀gbín Ológbojò ma ńké ni ó di Ẹ̀ṣà; said by Ẹ̀ṣà Ọ̀gbín when dancing about is regarded as iwì kíké (poem recitation); egúngún's poem. The speech of eégún is also called ẹ̀ṣà/ẹ̀ṣà pípè (the calling of Ẹ̀ṣà). From then and henceforth any masquerade that calls Ẹ̀ṣà is literally calling the first egúngún.

Òkòtòròjò
Ẹ̀ṣà is used to praise someone (à ń fi ẹ̀ṣà kí èèyàn), we use it to tell a story and events around (sọ ìtàn àti ìṣẹ̀lẹ̀ láwùjọ). Music is not left out in Ẹ̀ṣà (orin ò gbẹ́yìn pẹ̀lú lẹ́nu eégún), You will hear - :

"Mo jùbá onílé, ìbà àlejò, ìbà ọmọdé, àgbà. Ìbà eníyán, ìbà ènìyàn. Bí èkòló bá ti jùbá ilẹ̀ẹ́lẹ̀ á lanu, aṣọ ò ní ya méégún lórí. Èèwò!" 

"Modé modé, èmi ni eégún aláré-abì-koko-lẹ́tí aṣọ, èmi ni ọmọ apòòyìì rọinrọinrọin, èmi ni ọmọ atàkìtì, oníjó lẹ́sẹ̀, alóyinlóhùn

...............................................................

"Homage i pay to the house owner, visitors, young and old. Homage to the powerful (witches), homage to humans. 
The earth opens up to the earthworm when it pays homage to the earth. The eégún's attire will never tear on the eégún. Its a taboo! 

I have come, I have come, I am the show masquerade with knots at the elm of the cloth, I am the child who whirls around, the child that somersaults, the dancer, the one with sweet voice" 


The above poem; 
iwì/ewì eégún gives insight into the character, look of an egúngún, as well as its acrobatic displays as he performs.

You might have heard the word àgbà ọ̀jẹ̀  used as a figure of speech - àkànlò èdè to imply wisdom or wise one, professional (àwọn tí ó ní 
Òye). 




ìgbàlẹ̀

For instance, an announcement may go thus; àwọn àgbà ọ̀jẹ̀ nínú eré ìdárayá yóó wà ní ìkàlẹ̀ - professionals in sport will be at the event. Those regarded àgbà ọ̀jẹ̀ are renown for one thing or another. But in the real sense àgbà ọ̀jẹ̀ is an experienced person who is well drilled in the practice of eégún. Whereas, the word ọ̀jẹ̀ on the other hand, refers to a masquerade; all masqueraders in Yorùbá land are called ọ̀jẹ̀

In Yorùbá land, we have so many masquerades.  Apart from the father of masquerades eégún Ológbojò. Yorùbá masquerades includes ọya the fierce eégún. Alárìnjó/alágbe is an eégún in Ọ̀yọ́, which uses rags for its regalia. There is also eégún Ajóbíewé (masquerade that dance like a leaf), Ajófóyìnbó (dance for the whites), Alárànán in Ògbómọ̀ṣọ̀ (velvet masquerade) and others.




Dánáfojúrà is an egúngún who dances in fire.

In Èkìtì we have eégún yalawi, Ọ̀ṣáṣá, Àdó (the god of Ògún's masquerade), Ẹ̀pa or Òkòtòròjò/Ẹlẹ́fọ̀n; a masquerade with a kind of wound on its head. And also is Ẹdẹ̀

In Ìjẹ̀bú there is Ẹ̀lẹ́kú,  Awùrú, Elégbódo, Ìjẹ̀pà, Alápánsánpá and Gẹ̀lẹ̀dẹ́ a female affairs masquerade from Ẹ̀gbá. In Ìbàdàn we have Olóòlù, Siaba Ọ̀rányàn

In Lagos; Èkó we have Adímú-òrìṣà (Ẹ̀yọ̀), Ìgunnu; a tall masquerade which is up to 10 feet or above originates from Tápà

There is a very magical egúngún Àgan-òòṣà which is revered for its hopping steps when it walks. 

You may not know that, certain rituals are carried out in the 
egúngún groove on eégún festivals; onírúurú ètùtù la ń ṣe lọ́jọ́ ọdún eégún ní igbó ìgbàlẹ̀

Ètùtù Ẹ̀kú Eégúnmasquerade regalia ritual

Eégún are good dancers, they dance from house to house to collect gifts from the living. Anyone who refuse to give gifts will be flogged with ẹgba pàsán/àtòrí

Aside from dancing about on festival days, eégún's are used to break news of a dead person in the community. Once a renowned men die, 
egúngún will be seen in the streets speaking ewì  to inform the world that someone has joined the dead. And days before the burial, the egúngún comes out again to tell the family of the deceased that their loved one has arrived ọ̀run safely, after-which he will be presented food; oúnjẹ and wine; ẹmu.

Not just when someone dies, egúngún also comes out when a famous indigene celebrates an important event, when a king is enthroned, during chieftaincy ceremony and so on. 
Generally, we celebrate festival ọdún eégún from the 6th month Òkúdù through the 10th Ọ̀wàrà of the year, similar to Halloween.

Egúngún o ni ìwọ́ mọ̀? Apá ibo ló sì ti wá?

There are so many Yorùbá masquerade, do you know any and from where? 



Check out www.yobamoodua.org for more on Yorùbá education and information.


Friday, January 24, 2014

ÌGBÀGBọ́-ASÁN; SUPERSTITION

The elders will say "bí kò bá ní ìdí, obìrin kìí jẹ́ kúmólú" (if not for a reason, a woman will not be called kúmólú; Ikú-mú-olú - she will be in charge when all men olú are dead). Also, they often say bí a ṣe ń ṣe nílẹ̀ẹ wa, èèwọ ibòmíràn; that is to say, how we do it here, differs from how they do it elsewhere.

Àwá ń dọ̀bálẹ̀ lọ́kùrin - we do prostrate as men, obìrin á sì kúnlẹ̀ fágbà; while women kneel to greet elders. Because we know the value placed on respect for the elderly, we don't shake hands with an elder (torí a mọ ilà tí ìkíni tò n bíbọ̀wọ̀ fún ẹní juni lọ, a kìí bọwọ́ àgbà.

One proverb says that " ọmọdé tó bá mọwọ́ wẹ̀, á bágbà jẹun", a child that (knows how to wash his hands) respects the elder will dine with it. 

So why am i saying all this? It is because of the word "superstition" called  ìgbàgbọ́-asán in Yorùbá. Kí ló ń jẹ́superstition?  Is there an element of truth in it?



From the above screenshot, superstition arises from a religious point of view; Àwòrán òkè yìí sọ bí ọ̀rọ̀ náà ti ṣẹ̀ wá.

Ìbéèrè mi ni, ṣé òótọ̀ ni pé ìgbàgbọ́-asán ni àwọn ọ̀rọ̀ ti à mọ̀ sí ìgbàgbọ́-asán? My question here is, are all belief called superstition actually superstitions?  Which is why i started with the statement "bí kò bá ní ìdí, obìrin kìí jẹ́ kúmólú" which means that there is a reason behind everything, those primitive belief which are now regarded ìgbàgbọ́-asán all have an element of reality in them.

Ẹ jọ̀wó ẹ̀yin ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ bá wa dá síi, ṣé tòótọ́ ni pé #superstition láwọn ìṣe wa kọ̀ọ̀kan? Please my wise one, contribute to this, is it true that these believes are actually superstition?

Fún àpẹẹrẹ, kí ló mú àwọn àgbà Yorùbá ṣè'kìlọ̀ pé kẹ́nikẹ́ni má sú ìfé ń'nú òòrùn pé èyí ń fa ìgbóná, tàbí súùfé lálẹ́ bí kò bá ní'dí bí kò bá ṣẹlẹ̀ rí. (for instance, what made our elders warn that no one should whistle in the hot sun or else measles will infest the person's household, or whistle at night if such had never happened before).

Bọ́mọdé ò bátàn, á bá àrọ́bá baba Ìtàn 
(the child that met no story will meet analysis which is the father of story)


Don't you know that various Yorùbá events later became stories, proverbs - Ẹ ò mọ̀ pé onírúurú ìṣẹ̀lẹ̀ kan tì kejì ló ń dìtàn, di òwe. Maybe you do not know that the proverb "ṣe bí o ti mọ ẹlẹ́wà Ṣàpọ́n " is a statement by a beans seller in  Ṣàpọ́n a suburb of #‎Abeokuta in Ogun State Nigeria which is a proverb used till date.

You might also have heard the saying "orí ẹ pé bíi ti bàba Àlájọ #‎Somolu when the elders talk. It is a saying that originated from the wonderful acumen of a thrift collector; alájọ tó mọṣẹ́ ẹ̀ bíi ẹní mọlà ọwọ́, kò gbé'wé, ó sì mọ iye owó àjọ olúkúlùkù. Kò sì gbé àjọ Táyé fún Akẹ́yìndé rí. He, baba Àlájọ Ṣómólú never use a book to record his customers savings, yet he never gives someones else another persons contribution.

Ìtànjẹ ni, fáwọn òyìnbó láti sọ fún wa pe òtúbàntẹ́ láwọn nǹkan wọ̀nyí, torípé wọ́n mọ ihun wọ́n ń ṣe, àwa ló pàpà wá bájà, ọgbọ́n àti ta àṣà ti wọ́n fún wa ni gbogbo ẹ - it is a deceit for the English to call our believes are superstitious, as this now affects us, now we are engulfed in western cultures.

All is just an attempt for us to let go our realness, so we speak English, and forego our language regarded as vernacular - Ẹ wòó, akitiyan èèbó láti polongo èdèe rẹ̀ ló mú wa máa fọ̀'èbó, ká máa pe èdèe ti wa ni #‎Vernacular.

Àwọn ìṣe wa wo lo mọ̀ tí wọ́n kà sí #Superstition? Ẹ dá sọ́rọ̀ yìí - know of any of our belief regarded as 
ìgbàgbọ́-asán? 


Check out www.yobamoodua.org for more on Yorùbá education and information.

Sunday, January 5, 2014

Kọ́jọ́dá; Yorùbá New Year

In January, we wished friends, loved-ones a happy prosperous new year after the end of the Gregorian calender. 


GREGORIAN CALENDER

But do you know that Yorùbá has its indigenous calender? Even a Yorùbá new year, have you ever heard that?

That's right, we have our new year; dún tuntun,  distinct  from the Gregorian or Christian (onígbàgbó) and the Muslim (ìmàle) Hijra new year.

For your information, the Yorùbá  calender is called Kọ́jọ́dá. Traditionally, every 3rd day in June; Òkúdù is the entrance of a Yorùbá  new year. Approximately, year 2014 on the Yorùbá Kọ́jọ́dá will be dún 10056. Kọ́jọ́dá means may the day be foreseen. 


2008 KỌ́JỌ́DÁ BY REMI-NIYI ALARAN


Our ancestors - irúnmlẹ̀ have used the traditional Kọ́jọ́dá to foresee dates ọjọ́, festivals àjọ̀dún  and ceremonies ayy in time past (ayé àti)

Gradual lost - (ì)pàdán ní pele ní pele of 'our forefathers' baba ńlá wa heritage stems from the increase, varied European òyìnbó efforts ìyànjú, policies - ètò to make Africa forget gbàgbé our root (àṣà ìbílẹ̀ wa).


We know that the world over - a mọ̀ pé kárí ayé, the moon; òùpá serve ni as a means knowing time; aago in the olden days láyé ijọ́hun, and the sun oòrn was the day time ojú ọjọ́ while the moon is night alẹ́. This was how the days were divided into day-night. 



As the western culture is been imbibed by my people, our Kọ́jọ́dá was replaced, let to die for the Gregorian calender dates - ìṣe òyìnbó tó rinlẹ̀ ló mú kí a máa lo ìlànà ọjọ́ọ Gregorian dípòo tiwa n tiwa.

GREGORIAN CALENDER GOT TO AFRICA; EGYPT IN 1875 (COURTESY TONDERING.DK )

Four days make up a week in the Yorùbá calender (Kọ́jọ́dá) - Ọjọ́ mẹ́rin ni ọ̀sẹ̀ kan nílẹ̀ Yoòbá. Each day (ọjọ́ kànànkan is dedicated to a honour a deity or another (sì jẹ́ ọjọ́ ìbọ̀rìṣà kan), this correlates with modern day days of the week.

Deity (òrìṣà) of each Yorùbá day

  • First day of the week - Ọjọ́ kìníníọ̀sẹ̀ 

- Dedicated to honour Ọbàtálá (ọjọ́ ìbọ Ọbàtálá; Sọ̀pànná; Ìyáàmi; Egúngún)

  • Second day of the week - Ọjọ́ kejìọ̀sẹ̀

- A day for Ọ̀rúnmìlà: Èṣu; Ifá; Ọ̀ṣun (ọjọ́ fún Ọ̀rúnmìlà: Èṣu; Ifá; Ọ̀ṣun)

  • Third day of the week - Ọjọ́ kẹta ọ̀sẹ̀  

- Day reserved for Ògún; Oṣoosì (ọjọ́ òrìṣà  Ògún; Oṣoosì)

  • Fouth day of the week - Ọjọ́ kẹrin ọ̀sẹ̀  

- Dedicated to honour Ṣàǹgó; and wife Ọya (ọjọ́ fún òòṣà Ṣàǹgó, Ọya) 


The above shows which òòṣà is worshiped daily. Also, from January to December the 12 months have dedicated òrìṣà  festivals.  Later, the Kọ́jọ́dá had to be adjusted to synchronize with the modern calender with seven days (ọjọ́ méje), five working days - ọjọ́ òwò ṣíṣe márún, two weekends - ọjọ́ ìsinmi méjì.

Sundayọjọ́ Àìkú/ọjọ́-ọ̀sẹ̀/àko-ọjọ́ (day of immortality/first day of the week).
Mondayọjọ́ Ajé (day of profit, interest. Day Ajé came to ayé)
Tuesday ọjọ́ Ìṣẹ́gun (day of victory)
Wednesday ọjọ́ rírú (day of sacrifice)
Thursday ọjọ́ rúbọ;ọjọ́bọ (day of new creation, new dawn)
Friday  ọjọ́ Ẹtì  (day of deadlock)
Saturday ► ọjọ́ Àbámẹ́ta (day of three motions/suggestions)

Having said earlier - bí mo e s níàájú, we have ọjọ́ méje a week but the Yorùbá Kọ́jọ́dá has four - mẹ́rin. We have 91 weeks (ọ̀sẹ̀ àádọ́run-lé-mẹ́ta) on the Kọ́jọ́dá and 52 weeks (ọ̀sẹ̀ àádọ́taléméjì  on the western calender.


From these analysis - pẹ̀lú àlàyé yìí, the Yorùbá new year ọdún tuntun commences bẹ̀rẹ̀ ní June 3rd to end June 2nd of another year i.e June 3, 2014 to June 2, 2015 (ọjọ́ kẹ́ta oṣù Òkúdù sí ọjọ́ kejì oṣù Òkúdù ọdún tó ń bọ̀).

May i use this moment to wish you a happy Yorùbá new year - mo kíi yín kú ọdún tuntun.

Watch this video on YOUTUBE.


Check out www.yobamoodua.org for more on Yorùbá education and information.