Friday, July 26, 2013

EWÉ ÀTI EGBÒ (LEAVES, HERBS AND ROOTS)




EWÉ ÀTI EGBÒ
Every single plant, leave, tree stem, root; ewé àti ẹgbò on earth is for a particular use ìlòcure ìwòsàn, food oúnjẹ. 

In Genesis, Chapter one, verses 28, 29, 30 and 31, the bible indicated the value of plants as food, medicine for man  - he placed all plants, trees and shrubs, fishes in the ocean, birds in the air in our care and consumption. 



 Ní Gẹ́nẹ́sìsì orí kì-ní-ní, ẹsẹ̀ kejìdínlọ́gbn, ìwé mímọ́ ní - "
 Ọlọ́run sì súre fún wọn. Ọlọ́run sì wí fún wọn pé, Ẹ má bí sí i, kí ẹ sì gbilẹ̀, kí ẹ sì ṣe ìkáwọ́ rẹ̀, kí ẹ sì ma jọba lórí ẹja òkun, àti lórí ẹyẹ ojú-ọ̀run, àti lórí ohun alàyè gbogbo tí ńràkò lórí ilẹ̀. 

Ẹsẹ̀ kankàndínlọ́gbn - Ọlọ́run sì wípé, kíyè sí i, Mo fi ewéko gbogbo tí ó wà lórí ilẹ̀ gbogbo tí ńso èso fún nyín, àti igi gbogbo nínú èyítí i ṣe igi eléso tí ńso; ẹ̀yin ni yíò ma ṣe oúnjẹ fún. 

Ẹsẹ̀ kankànlélọ́gbn - Ọlọ́run sì rí ohun gbogbo tí ó dá, sì kíyèsi i, dáradára ni..." 

Some people claim that plants, herbs, roots are evil and bad for our consumption. When our fathers had studied the efficacy of plants; leaf, stem, root, seed and they know what it cures or heals in the body -


Ẹ wá ní kí á má jáwé kámá wa egbò tí Elédùà dá fún ìlò ọmọ aráyé. Nígbà tí àwọn baba wa jágbọ́n ewé oníranànran, tí wọ́n mọn orúkọ téwé ńjẹ́, wọ́n ṣe ìwádìí tó yanrantí, wọ́n mọn iṣẹ́ tí ọ̀kàn-kan ńṣe lágọ́ ara


In Yorùbá, these herbal medicine is often called ẹgbògi (ẹgbò igi).

Industrialization; ilẹ̀ iṣẹ́ lẹ́r ńlá-ńlá, civilization; ̀làjú and western religion played a role in killing the African Yorùbán traditional herbal medicine. The brainwash of my people, making them see nature as possessing evil spirits; ẹ̀mí òkùnkùn, whereas, it is the industrialization, westernization ideology that is the evil haunting the black race and the world in general. It is pure lie that to use plants for healing is demonic. 


Did He not create; dá everything; gbogbo nǹkan on earth (ayé) for man's use? ÈdùmàrèGod  has made them all ńbig and kékeré small for human use and consumption (Èdùmàrè dá gbogbo nǹkan láyé fúlílò àti jíj m èèyàn). 


Plants have oró; chemicals in them, it is this chemicals that does ìyanu wonders in the body system (ara)when consumed by human; èèyàn. The Yorùbá know this, which is why our fore fathers; baba ńláa wa use foray of plants as medicine and food to cure various àìsàn; ailments.




Knowing the efficacy of plants takes years (Ọdún) of practice. It is either one is born into a family of oníṣègùn; herbalists or one is an apprentice - ỌmỌ ìkọ́ṣẹ́ under an ifá priest; babaláwo to be able to tell what each and every plant, stem and root was created for and what illness it will cure - kí ọmọ ìkọ́ṣẹ tó ó mọ ìwúlò àti àìsàn tí èwè kọ̀̀kan nínú igbó ń wòsàn, yóó ti kọ́ṣẹ́mọṣẹ́ fún ọdún kan gbáko.

It is not that any oògùn; charm or incantation f̀ what so ever is recited onto the herbal plant; ẹgbògi , but these plants have innate potency as made by Èdùmàrè; God the creator. In most cases, all the babaláwo have to say is just a word of
àẹ/ìwúr; to bless the plant to display its potency in the body system of the user/patient; alàìsàn through f̀.

Just as sugar from oyin ìgàn; bee honey is rich and natural, so is the medicine from plants which can not be compared to industrial sugar which is artificially dangerous to the human health. 

Do you know that chewing the stick of dongoyaro restores man power in men? It has no side effect, unlike Viagra and other steroids  which destroys the human system (àwọn nǹkan a fi oògùn òyìnbó gbìn, ṣe ò dára fún ìlera ọmọ ènìyàn?).






The Babaláwo; doctors often use ewédú; cochorus leave during labour; j́ ìkúnlẹ̀  when a pregnant woman; aláboyún finds it difficult to deliver of a baby; m ìkókó. Once the ewédú plant has been drank or inserted into the mother, she immediately delivers.

Not until the patient; aláìsàn had contacted the Babaláwo, the oníṣègùn; pharmacist will not be able to prescribe any remedy or herbs. Ifá is conducted to know which herbs; àgbo to be prescribed.


Igi mángòrò 

Orógbó; bitter kola is a great source of antibiotic on planet earth. The ògì; pap made out of maize, sorghum is also a very good source of anti-bacterial/cleansing food. 


Amaranthaceae; dágunró is a pain reliever, when rubbed on the affected area. Almost everyone in Yoruba land is familiar with Mangifera Indica; m
ángòrò as a cure for body fever when boiled in clay pot; ìkòkò and its water is taken as a drink. Haw-life plant; ̀dùndùn is used as a remedy for convulsion. Its leaves heated with fire, liquid extracted and taken orally or used to massage the patients body. 








ÒríShea butter, a whitish or yellowish substance extracted from a type of tree is use to massage the body (ẃra; wọ ara)to reduce pain; ìrora, applied on boil to get out the abscess- yún



Gbúre


The plant known as giant milk weed; ewé bomubómú works wonders for measles, diarrhea, leprosy, eczema, ringworm, asthma, convulsion etc. A ó já ewé bomubómú a ó fi ògógóró gbo ó. We pluck some leaves of the bomubómú plant, we squeeze out the juice with local hot drink.
Ewé bomubómú
Oní ìta a máa mu gàásì kànànkan láàárọ̀ àti lálẹ́, á sì máa fi pa ara - the measles patient will take a shot of the bomubómú juice morning, night and rub the juice on the body. 
Yàtọ̀ sí ká fi ewé bomubómú ṣe àgbo, àwọn oní-wàrà ò lè ṣe láì má rẹ́ ewé bomubómú sínúu wàrà. Apart from the listed uses, the cheese; wàrà makers cannot do without slicing some bomubómú leaves into the delicacy. Ni àwọn àgbà fi ní " àjẹjù wàrà ló ńmu ni je bomubómú. This is why elders say “over eating of cheese, makes one eat the giant milk weed”.

Ewé òmísínminsìn
Crabs eye or rosary pea plant seeds; èso ojú ológbò, the plant itself is known as òmísínminsìn. The plant when chewed has a sweet taste (ewé òmísínminsìn a máa dùn bí a bá múu sẹ́nu). In Yorùbá land, the leave of the plant, seed and root are soaked in local hot drink – ògógóró, and is been used to send cough, cold, convulsion parking.   

Bí a kó ewé mọ́ èso, ìtàkùn òmísínminsìn kí a bọ̀ ọ́ tàbí kó o sínúu ọtí ògógóró, oògùn ikọ́, òfìkìn, gìrì, ale, ọgbẹ́ inú délẹ̀ nìyẹn - when the leaves, seed, root are boiled together or soaked in local hot drink, cough, cold, convulsion, aphrodisiac, stomach ulcer medicine is ready. 

It is true that the avocado pear is not a native of Africa, but since it was brought here, we have been using it seed has remedy for various ailments.

Díẹ̀ lára ìwúlòo kóró inú èso pear yìí ni 'wọ̀nyí (a little benefit of the pear seed are):
Afọ̀dọ̀tí : a cleanser
Alárùn-un ọkàn, jẹjẹrẹ: heart problem cure and cancer cure & prevention
Adín ìgbẹ́ gbuuro kù: diarrhea stopper
Àgúnmu
• Kóró inú èso pear pẹ̀lú dáa fún alátọ̀sì – the seed is also good for persons with toilet infections, ọlọ́gbẹ́ inú - ulcer, and alárùn-un ìbálòpọ̀ – sexually transmitted disease.


After eating jẹ the soft fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ edible part, the seed kóróo will be dried gbẹ, blended lọ̀ ọ́ fine kúnná and made into powder ebu called àgúnmu.

>>See :
1.  herbal plants
2. Yorùbá herbs
3. Yoruba vegetables


Àgbó wo nìwọ́ m
ọ̀? - What herb do you know? 



Check out www.yobamoodua.org for more on Yorùbá education and information.

Friday, July 19, 2013

Yẹ̀yẹ́ Àwọn Aṣòfin Wa


Orísìírísìí ohun ẹlẹ́yàmẹ́lẹ́yá la ó máa rí nílú wa, Nàìjíríà. Ẹ ní kí ló dé? Ti ìwà ìbàjẹ́ àwọn 'arúfin' àbí aṣòfin ní wọ́n ń pera wọn ló mú mi kọ àròk yìí.

We witness various funny happenings in our country, Nigeria. Did you say why did i say so? It is the bad attitudes of our 'law breakers' or is it law makers prompted this essay.

Ẹ ò rí ìranù, ìwà àbùkù tí àwọn aṣòfin wọ̀nyìí ń dánwò, lójú ran ọmọ aráyé. Ọpẹ́lọpẹ́ òmìnira àwọn oníròhìn tòhun ẹ̀r ayélujára à bá má ti lánfààni láti rí yìí wo tàbí gbọ́ nípa rẹ̀ rárá. 

Can you see the nonsense our lawmakers are displaying in the viewing eyes of the world? Thank God for Press Freedom and the internet, we wouldn't have heard or seen this disgraceful act by our law makers.

<T ÀWÒRÁN YÌÍ KÍ ORÍ Yẹ̀Yẹ́ ÀWọN AṣÒFIN WA NÍ YORÙBÁ>

Bàbá ẹnìkan ló ń la irin mọ́ bàbá ẹlòmíràn lórí yìí, àfi bíi kó pa á, àfi bíi kókúkú kú dànù. Torí kíni, torí ipò, torí owó ìjókòó tabua tí wọ́n fi ń ṣara rindin. Ó ga o, àwọn ọmọ ìta ló ńṣòfin, ṣèlu fún wa. A tí ń rí àṣemáṣe nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin ọpẹ́ díẹ̀, àmọ́ tí ìpínlẹ̀ Rivers yìí kọjá bẹ́ẹ̀. Ṣé bí yóó ṣe má a rí lọ rè é?

This is someone's father hitting a piece of metal on another person's father, he almost killed him. All for the post and the exorbitant sitting allowances. It's a pity, we have hooligans  as our lawmakers and rulers. We have been witnessing such mayhem in the houses of assembly but the case of Rivers State is beyond it. Is this how it will continue?

Àga ìjókòó la mọ̀ tí wn s lu ira wn bíi èdè-òyédè bá bẹ́ sílẹ̀ nínú ìpàdé wọn, nígbà mìíràn ẹ̀kẹ̀ṣẹ́ ni wọ́n fi ń fọ́ ra wọn lẹ́nu, ṣùgbọ́n tí ilẹ̀ Rivers tí a ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí kọjá àfẹnusọ.

We know of chair throwing during their meeting, and sometimes exchange of punches, but this Rivers crises is beyond chair throwing or punches.

Àwn Yorùbá ló spé, "bí a ṣé ń e nílẹ̀ wa, èwọ̀ ibòmíràn ni" bẹ́ẹ̀ ni ti orílẹ̀-èdèè wa erí, àwn jgúdújrá, bámúbámú ni mo yó mi ò mọ̀ pé ebí ń pa ọm nìkán àn kan ni òṣèlú tí a ní.

Yoruba said 'the way we do it in our land, differs from how it is been done somewhere else' thus is the Nigerian case, it is greedy rulers that we have.

Ta ni yóó wá ba wa túnlẹ̀ wa tò, ìkan ò gbé kan, irúkankan náà irúworúwo bẹ̀ gbẹ̀gìrì, oníjàgídíjàgan ló pọ̀ lára àwn adarí ìjba wa. Ijọ́ wo la ó ṣè yìí dà?.


Who will change our system for us? Our leaders are birds of a feather, when will shameful acts like this cease to occur?