Subscribe Now: RSS feed

Wednesday, 23 January 2013

NÍPA ỌMỌ YOÒBÁ
Hi there, 
I am Ọmọ Yoòbá, a 21st Century young Yorùbá man, with the mind of a 18th Century old man. 

Am a true Yoòbá boy, I love my culture. 
I love Yorùbá.

I call on you Yorùbá sons & daughters, home or away, to visit here for the Yorùbá culture.

Want to learn the Yorùbá culture? Want to know more about the Yorùbá tradition? Join me right here, on YO’BA MO’ODUA 


Báwo ni o, orúkọ mi ni Ọmọ Yoòbá. Mo sì n'ífẹ́ẹ̀ sí èdè, àṣà àti ìṣe 
ọmọ káàárọ̀-o-ò-jí i re, èyí ló mú mi tọ́pẹpẹ ètò 
YO’BA MO’ODUA lórí ẹ̀rọ ayélujára, fún gbogbo ọmọ Yorùbá láì yọ àwọn olólùfẹ́ èdèYorùbá sílẹ̀.

darapọ̀ mọ́ wa, kí ẹ kọ́ ọgbọ́n kan tàbí òmìran nínú àṣà baba wa O'òduà.

Ẹ rántí láti padà wá o. Ire o!!!